Lyrks
Lyrks
Cover Art

Iba Lyrics by Aṣa

Aṣa

0

[Intro]
Ọrun ṣ'ilẹkun, I wanna have some talk with you

[Verse 1]
Nítorí rẹ mọ ṣe l'ọlá
Nítorí rẹ mọ ṣe ń ṣ'oge
Nítorí rẹ mọ ṣe ń ra moto
Mo wọle, mọ b'Olúwa mi s'ọrọ
Nítorí rẹ mọ ṣe wá l'ayé
Nítorí rẹ mọ ṣe wo aṣọ s'àrà
Nítorí rẹ mọ jí l'òwúrò
Mo wo ayé mi n'ọdẹ ye, ya

[Chorus]
Ah o, Ah-ah o, ah o iba f'Ẹledua
Ah o, Ah-ah o, ah o
Mowole, mo b'Olúwa mi sọrọ

[Verse 2]
Nítorí rẹ mọ ṣe ń gbó ìròyìn ayọ
Lai s'owó, lai sì nkan kan
Ìyà òní l'ayo ọla o, b'Olúwa ti wi bẹ náà lórí

Jiji moji lowuro
Moji si inu ipese re
Ayo at'alafia ye ye

O, o o oni pe ki n ma se beru

A o, Aa a o o ibafeledu'a
A o, Aa a o o
Mowole, M'obolowa mi soro

Melo la fe so
Melo lo si n bowa
Melo la fe so, eh
Melo lo si n bowa

Nitori re mose n sa ko, everyday, eh eh
Nitori re mojijo lese mi, oh oh oh, oh oh
Ninu iponju, Ninu idamu
B'ebi ba n p'ona
Mawole, maboluwa mi soro

B'emi o le yan
Baye ba foju dimi
B'emi o le ni
Mawole, maboluwa mi soro

A o, Aa a o o ibafeledu'a
A o, Aa a o o
Mowole, M'obolowa mi soro

Nínú ìpọ́njú, nínú ìdààmú
B'ẹbi ba ń p'ona, má wó ile ma b'Olúwa mi s'ọrọ
M'oní f'ojú sunkún mo
Aye loja, oh oh... Orun... Orunile
And that's fine by me... Eh eh...
Oh... Ye ye... Bring it down... Oh oh...
Credits

About “Iba” by Aṣa

Read the complete lyrics to "Iba" by Aṣa from the album "Aṣa". On Lyrks you can follow along with the full text, explore the artist's discography, and discover related songs. The track is often categorized under Pop, Nigeria, Yoruba.

"Iba" is performed by Aṣa. from the album "Aṣa" This page provides the full lyric text for fans who want to sing along, study the songwriting, or compare versions across releases. Lyrks organizes lyrics by artist and song slug so you can bookmark and share a stable URL. Music lyrics help listeners connect with emotion, narrative, and rhythm in a track. Whether you are learning English, researching a favorite chorus, or preparing for karaoke, having accurate line breaks and section labels (verse, chorus, bridge) makes the experience easier. We link to the official artist profile on Lyrks where available, including biography snippets, top songs, and chart placements when we have that data. If you enjoy "Iba", explore more songs by Aṣa using the links below. Chart and trending pages on Lyrks highlight what listeners are searching for this week. For copyright or correction requests, see our DMCA and contact pages.

View all songs and biography for Aṣa · Trending lyrics · Billboard Hot 100

Frequently asked questions

"Iba" is credited to Aṣa. Songwriting credits may include additional writers listed on the release; check the credits section on this page for linked collaborators.

"Iba" appears on "Aṣa".

Visit the Aṣa artist page at /artist/asa for biography, popular tracks, and links to more lyric pages.


Lyrks
Lyrks

Your gateway to the world of music lyrics.

Product

Features


© 2026 Lyrks. All rights reserved.