Lyrks
Lyrks
Lyrks
Cover Art

Oba Awon Oba Lyrics by Hibeekay

0

Omobadeji:
Kabiyesi Olodumare ekun oko oke pharaoh
Oba nla ti nfi oba je
Oba to ju oba lo, Oba awon oba
Aterere kari aye, atorise, ameda aweda aseda
Emi o to lati yin o o, Olorun awon baba wa
Ti nje emi ni, emi ni, emi ni Mo ke Kabiyesi o
Oba awon oba, Oba awon oba Oba awon oba, Oba awon oba
All: Oba awon oba, Oba awon oba Till fade.......
Hibeekay:
Tani eni ti o ba esu wi
To da aye ati orun
Gbongbo idile jese
Akobi ninu awon oku
Kiniu eya juda
Apata ayeraye
Ologo didan ni
Kabio osi Olorun
Olowogbogboro ni
Ti nyo omo re lofin aye
Alagbada ina
Oba ayeraye
Oba ti o la omi okun pupa
To gba omo Israeli
Lowo ogun pharaoh
Awon ara egipti
Oba to ju oba lo
Ibeere ati opin
Olorun Abraham
Olorun Isaaki
Olorun Jakobu
Olorun Dafidi
Akin Omo Akin:
Oba aja bi iji
Olorun ailopin
Agbafefe sola
Pari pari aye
Eni mimo ola
Onibudo eye
Aara wawa nwowoo
Pitu pitu ola
Adakeroro seun lile
Oba akoda aye
Oba aseda orun
Akiikitan Ayiinyintan
Iwo naa ni
Oba tole logun
Mimo mimo mimo
Eleburu ike
Oba onibu ola
Oba onibu ore
Akasebijo bawon wi
Ipa lori ipa
Abani dinbe lai jeran
Ajanaku ode orun
Weli weli bi ejiinpani
Funfun nini lode orun
Akobi akorii
Ako oju tole logun
Oba aseyi to fe
Asegun ma lo ibon
Oke ninu ogbun
Odaada tii ri da
Odaada tii ri da
Dagi lekun esoo
Agba ninu eko
Onibudo eye
Aboni ma jeun
Afuye bi ewe
Awuwo bi erin
Kabiyesi ode orun
Afoba joba
Ganaku bi oyun
Gulutu bi omo
Agbekumi ma bi
Olori oloore
Gboun gboun bi owuu lurin
Akeni bi oju
Atoni bi omo
Kosoba bi ire
Aponni ma gba oja
Asoni ma sun lo
Oba ayeraye
Titi lae lae lae lae lae lae lae lae lae ni un o ma yin o nigbagbogbo...
Credits

About “Oba Awon Oba” by Hibeekay

Read the complete lyrics to "Oba Awon Oba" by Hibeekay. On Lyrks you can follow along with the full text, explore the artist's discography, and discover related songs. The track is often categorized under Pop.

"Oba Awon Oba" is performed by Hibeekay. This page provides the full lyric text for fans who want to sing along, study the songwriting, or compare versions across releases. Lyrks organizes lyrics by artist and song slug so you can bookmark and share a stable URL. Music lyrics help listeners connect with emotion, narrative, and rhythm in a track. Whether you are learning English, researching a favorite chorus, or preparing for karaoke, having accurate line breaks and section labels (verse, chorus, bridge) makes the experience easier. We link to the official artist profile on Lyrks where available, including biography snippets, top songs, and chart placements when we have that data. If you enjoy "Oba Awon Oba", explore more songs by Hibeekay using the links below. Chart and trending pages on Lyrks highlight what listeners are searching for this week. For copyright or correction requests, see our DMCA and contact pages.

View all songs and biography for Hibeekay · Trending lyrics · Billboard Hot 100

Frequently asked questions

"Oba Awon Oba" is credited to Hibeekay. Songwriting credits may include additional writers listed on the release; check the credits section on this page for linked collaborators.

Album information for "Oba Awon Oba" is not available in our database yet. You can still read the full lyrics on this page.

Visit the Hibeekay artist page at /artist/hibeekay for biography, popular tracks, and links to more lyric pages.