Lyrks
Lyrks
Lyrks
Cover Art

The Restorer (Olurapada) Lyrics by JayMikee

2023

E ba mi ki Olurapada
E ba mi ki Olurapada
Nitori to shey oun pupo fun Omo araye
Nitori anu re duro Lai Lai
E bami ki Olurapada
E bami ki Olurapada
Apata aye raye mo ki o o baba mi
Alagbara giga giga giga
Alagbara to n gba mi lowo ajunilo
Kii ba ti la gbara re
Ko se un ti la gbara re
Olugbala
Oludande
Olurapada
Olugbeja
Oluranlowo
Ata aiye se e e
Ato rise
Mo ti Fi Jeus shey abo Oun ni ibi isadi mi
Lowo lowo iranlowo baba ti dide iranlowo fun mi
A ti gbemiga Ori Apata aye raye a ko ni shi mi ni po rara
A ti ramipada
A ti so mi do omo
Mo jade ninu Idalebi
Ah ah ah ah Mo gba idalare
Ninu Jesu Oluwa
E ba mi ki Olurapada
E ba mi ki Olurapada
Nitori to shey oun pupo fun Omo araye
Nitori anu re duro Lai Lai
E bami ki Olurapada
E bami ki Olurapada
Ara ba ri biti
Ari bi rabata
Gba ni gba ni ti aye n saya
Gba ni gba ni ti Orun n bo
Olori Ogun
Asaju Ogun
Akeyin Ogun
Akikanju loju Ogun
Iwo la gba ni lowo ija
Baba mi arogun da ade
Arogun ma ti di
Olugbeja Mi oh oh oh
Gba ni gba ni
Mu ni mu ni
Yo ni yo ni
La ni la ni
Olusegun
Aja segun
O gbe ni ni ija ke ru o bonija lojo ija
Baba mi onikan gbe rare nija
Ta ni Iwo oke ni waju Zerubabeli
Lojiji odi dan dan ki e di ite mole
Mo gboju mi soke ni bi iranlowo mi yio a ti wa
Iranlowo mi n be ninu oruko oluwa ah ah ah ah
A ti gbe mi nijaaa
Mo ti ju asegun lo
E ba mi ki Olurapada
E ba mi ki Olurapada
Nitori to shey oun pupo fun Omo araye
Nitori anu re duro Lai Lai
E ba mi ki Olurapada
(Chants)...
E ba mi ki Olurapada
E ba mi ki Olurapada
Nitori to shey oun pupo fun Omo araye
Nitori anu re duro Lai Lai
E ba mi ki Olurapada
E ba mi ki Olurapada
Credits

About “The Restorer (Olurapada)” by JayMikee

Read the complete lyrics to "The Restorer (Olurapada)" by JayMikee in 2023. On Lyrks you can follow along with the full text, explore the artist's discography, and discover related songs. The track is often categorized under Afrobeat, Pop.

"The Restorer (Olurapada)" is performed by JayMikee. in 2023 This page provides the full lyric text for fans who want to sing along, study the songwriting, or compare versions across releases. Lyrks organizes lyrics by artist and song slug so you can bookmark and share a stable URL. Music lyrics help listeners connect with emotion, narrative, and rhythm in a track. Whether you are learning English, researching a favorite chorus, or preparing for karaoke, having accurate line breaks and section labels (verse, chorus, bridge) makes the experience easier. We link to the official artist profile on Lyrks where available, including biography snippets, top songs, and chart placements when we have that data. If you enjoy "The Restorer (Olurapada)", explore more songs by JayMikee using the links below. Chart and trending pages on Lyrks highlight what listeners are searching for this week. For copyright or correction requests, see our DMCA and contact pages.

View all songs and biography for JayMikee · Trending lyrics · Billboard Hot 100

Frequently asked questions

"The Restorer (Olurapada)" is credited to JayMikee. Songwriting credits may include additional writers listed on the release; check the credits section on this page for linked collaborators.

Album information for "The Restorer (Olurapada)" is not available in our database yet. You can still read the full lyrics on this page.

Visit the JayMikee artist page at /artist/jaymikee for biography, popular tracks, and links to more lyric pages.